|
Hello, I am a United States Marine. |
|
|
en leh o, shoja maa ree nee ee leh amareeka nee mee |
|
Ẹ'nlẹ́ o, ṣọ́jà màrínì ilẹ̀ Améríkà ni mí |
|
|
Hello, I am a United States Soldier. |
|
|
en leh o, shoja ee leh amareeka nee mee |
|
Ẹ'nlẹ́ o, ṣọ́jà ilẹ̀ Améríkà ni mí |
|
|
May peace be upon you. |
|
|
a laa fee ya fU eh |
|
Àláfíà fún ẹ |
|
|
With whom would you like to meet? |
|
|
taanee o feh shay ee Pa day Peh loo? |
|
Tani o fẹ́ ṣe ìpàdé pẹ̀lú? |
|
|
Do you have an appointment? |
|
|
shay eh tee jo Peh no ee Pa day yee teh leh? |
|
Ṣé ẹ ti jọ pẹnu ìpàdé yì í tẹ́lẹ̀? |
|
|
What time is your appointment? |
|
|
ee Ba wo nee ee Pa day reh? |
|
Ìgbàwo ni ìpàdé rẹ? |
|
|
Please demonstrate using your fingers. |
|
|
jo wo fee awoH ee ka reh jo weh |
|
Jọ̀wọ́ fi àwọn ìka rẹ jú'wé |
|
|
Please wait while I check if he is in the compound. |
|
|
jo wo doroo keen wo boo ya o wa nee no o Ba |
|
Jọ̀wọ́ dúró kí n'wo ò bóyá ó wà nínú ọgbà |
|
|
Do you have information concerning anti-coalition activity? |
|
|
shay o mo nee Pa ee Be mo laatee shay wa nee ka? |
|
Ṣé o mọ̀ nípa ìgbìmọ̀ láti ṣewá n'íkà? |
|
|
Please wait while I contact Marine investigators. |
|
|
doroo day mee kee in lo so fU awoH shoja maa ree nee o loo waa dee |
|
Dúró dèmí kí nlọ sọ fún àwọn ṣọ́jà màrínì olùwádì |
|
|
Please check again in a week. |
|
|
jo wo Pada waa nee o seh ko |
|
Jọ̀wọ́ padà wá ní ọ̀sẹ̀ kan |
|
|
Before entering the compound, I have to search you. |
|
|
mo nee laatee beh wo kee o to lay wo ee no o Ba |
|
Mo ní láti bẹ̀ ẹ́ wò kí o tó lè wọ inú ọgbà |
|
|
Please proceed to the search area. |
|
|
jo wo lo see ee bee ee beh wo |
|
Jọ̀wọ́ lọ sí ibi ìbẹ̀wò |
|
|
I can only search one person at a time. |
|
|
ee ko ko nee mo lay shay ee beh wo |
|
Ìkánkan ni mo lè ṣe ìbẹ̀wò |
|
|
Please show me your identification. |
|
|
jo wo fee ee weh reh haH mee |
|
Jọ̀wọ́ fi ìwé rẹ hàn mí |
|
|
Are you in possession of any weapons? |
|
|
shay o wo ee ja waH laara reh? |
|
Ṣé ohun ìjà wà lára rẹ? |
|
|
If so, I must hold onto your weapon while you are in the compound. |
|
|
tee o ba jeh banee, maa laatee moo ohn ee ja reh da nee fU a ko ko tee o waa nee no o Ba |
|
Tí ó bá jẹ́ bẹ́ ẹ̀ ni, mà á láti mú ohun ìjà rẹ dání fún àkokò tí o wà nínú ọgbà |
|
|
I will return it to you when you leave. |
|
|
maa see da ohn ee ja reh Pa da fU eh nee a ko ko tee o ba ohn lo |
|
Mà á sì dá ohun ìjà rẹ padà fún ẹ ní àkokò tí o bá nlọ |
|
|
Please spread your feet shoulder width apart and hold your hands up. |
|
|
jo wo ya eh seh reh may jay jee, ko see ka wo reh sokay |
|
Jọ̀wọ́ ya ẹsẹ̀ rẹ méjèjì, kósì k'áwọ́ rẹ s'òkè |
|
|
Thank you for your cooperation. |
|
|
o shay fU ee fo wo so wo Po reh |
|
O ṣé fún ìfọwọ́sowọ́pọ̀ rẹ |
|