Get Instructions
main picture
Title Bar
Go To Main Menu Print Page previous page PagePage Total next page
Play Button Warning, United States Soldiers will be conducting a search of the area! Play Button ee shoora, awoH shoja ee leh amaree ka feh shay ee bay wo aBeBe yee! Ìṣọ́ra, àwọn ṣọ́jà ilẹ̀ Améríkà fẹ́ ṣe ìbẹ̀wò agbègbè yì í!
Play Button We are looking for individuals who are planning attacks against ___ and coalition forces. Play Button a ohn wa awoH eh nee yo tee o ohn shay ee Be mo laatee shay awoH ___ a tee shoja wa nee jaam ba À nwá àwọn ènìyàn tí ó nṣe ìgbìmọ̀ láti ṣe àwọn ___ àti ṣọ́jà wa ní 'jàmbá
Play Button We are looking for weapons that are being used to hurt ___ and coalition forces. Please prepare your home for inspection! Play Button a ohn wa awoH own ee ja tee woH ohn lo laatee shay awoH ___ a tee shoja wa nee ka. eh moora ee lay yee see leh fU a bay wo! À nwá àwọn ohun ìjà tí nwọ́n nlò láti ṣe àwọn ___ àti ṣọ́jà wa ní'kà. Ẹ múra ilé yín s'ílẹ̀ fún àbẹ̀wò!
Play Button We are here to help the Nigerian people. Play Button a wa laatee raH awoH omo nay jee ree ya lo wo A wá láti ràn àwọn ọmọ Nàíjíríà l'ọ́wọ́
Play Button Please be advised that soldiers will not hesitate in defending themselves if threatened. Play Button mo feh kee eh mo we Peh awoH shoja aa Pa eh nee kay nee tee o feh shay wa nee ka Mofẹ́ kí ẹ mọ̀ wípé àwọn ṣọ́jà á pa ẹnikẹ́ni tí ó fẹ ṣe wá n'íkà
Play Button We greatly appreciate your cooperation. Play Button a doo Peh gaH fU ee fo wo so wo Po reh A dúpẹ́ gan fún ìfọwọ́sowọ́pọ̀ rẹ
Play Button Please open your doors. Play Button jo wo shee BoBo ee leh koo reh Jọ̀wọ́ ṣí gbogbo ilẹ̀kùn rẹ
Play Button Remain outside in your yard until the search is complete. Play Button doroo see ee ta nee ee wa jo ee lay reh tee tee ee bay wo aa fee Pa ree Dúró sí ìta ní iwájú ilé rẹ títí Ìbẹ̀wò á fi parí
Play Button When the soldiers arrive at your house, the homeowner can walk them through the search. Play Button tee awoH shoja ba day ee lay reh, o nee lay lay moo woH shay ee bay wo Tí àwọn ṣọ́jà bá dé ilé rẹ, onílé lè mú nwọn ṣe Ìbẹ̀wò
Play Button We are not here to harm anyone. Play Button a ko wa laatee shay eh nee kaa nee nee ka A kò wá láti ṣe ẹnikẹ́ni n'íkà
Play Button Our goal is to increase security in the area. Play Button a wa fU ee lo see wa jo ee da bo bo nee aBeBe yee A wá fún ìlọsíwájú ìdábòbò ni agbègbè yì í
Play Button Thank you for your cooperation. Play Button o shay fU ee fo wo so wo Po reh O ṣé fún ìfọwọ́sowọ́pọ̀ rẹ
Play Button You are permitted to have a weapon to defend your home. Play Button a fU eh laa yee laatee nee own ee ja fU ee da bo bo ee lay reh A fún ẹ l'áyè láti ní ohun ìjà fun ìdábòbò ilé rẹ
Play Button The soldiers will not seize weapons used for home security if the homeowner identifies them to us before we find them. Play Button awoH shoja ko nee Ba awoH own ee ja tee o wa fU ee da bo bo ee lay, tee o nee lay ba fee haH wa kee a to ree woh Àwọn ṣọ́jà kò ní gba àwọn ohun ìjà tí ó wà fún ìdábòbò ilé, tí onílé bá fi hàn wá kí a tó rí nwọn
Play Button If the soldiers find unauthorized weapons in the house or yard the homeowner will be apprehended. Play Button awoH shoja yo moo o nee lay tee woh ba ka awoH own ee ja tee ko wa fU ee da bo bo mo ee no ee lay ta bee leh Beh ee lay reh Àwọn ṣọ́jà yíò mú onílé tí nwọ́n bá ká àwọn ohun ìjà tí kò wà fún ìdábòbò mọ́ inú ilé tabi l'ẹ́ẹ̀gbẹ́ ilé rẹ̀
Play Button Please place all authorized weapons outside on the ground, at least three meters away from any person. Play Button jo wo ko BoBo own ee ja tee o ba o fee moo see leh nee ta, kee woH see fee, o kay ray jo, mee ta mey ta jee no see eh nee kaa nee Jọ̀wọ́ kó gbogbo ohun ìjà tí ó bá òfin mu sílè níta, kí nwọ́n sì fi, ókéré jù, mítà mẹ́ta jìnà sí ẹnikẹ́ni
Go To Main Menu Print Page DLIFLC 2007 previous page PagePage Total next page