Get Instructions
main picture
Title Bar
Go To Main Menu Print Page previous page PagePage Total next page
Play Button What communicable diseases in the local population pose the greatest risk to visiting foreigners? Play Button kee nee awoH aa rU nee aBeBe yee tee o jeh ee woo ohn laa fU awoH a lay jo laa tee o ree leh ee day meeraH? Kíni àwọn aàrùn ní agbègbè yì í tí ó jẹ́ ewu nlá fún àwọn àlejò láti orílẹ̀ èdè mìràn?
Play Button What medical conditions are the most common cause of death in this area? Play Button kee nee ohn aa ee lay raa tee o on Pa awoH ee nee yaH joo nee aBeBe yee? Kíni ohun àilera tí ó n pa àwọn ènìyàn jù ní agbègbè yì í?
Play Button Who is the local physician in this area? Play Button taa nee do kee taa ee bee leh nee aBeBe yee? Tani dókítà ìbílẹ̀ ní agbègbè yì í?
Play Button Where is he located and how can I contact him? Play Button ee bo nee o waa aa tee Pay baa wo nee mo shay lay ree? Ibo ni ó wà àti pé báwo ni mo ṣe lè rí i?
Play Button What parasites exist in local food and water? Play Button awoH ko ko roo aa rU wo nee o wa nee no ohn jeh aa tee o mee ee bee leh? Àwọn kòkòrò aàrùn wo ni ó wà nínú oúnjẹ àti omi ìbílẹ̀?
Play Button What diseases infect newborn children? Play Button awoH aa rU wo nee o maan moo awoH o mo tUtU? Àwọn aàrùn wo ni ó má a n mú àwọn ọmọ tuntun?
Play Button What chemical residues or foreign substances exist in the environment and may contribute to illness? Play Button awoH kaa mee kaa lee taa bee ohn ko wo nee no a feh feh tee o lay fa aa ee lay raa? Àwọn kẹ́míkàlì tàbí nkan wo nínú afẹ́fẹ́ tí ó lè fa àilera?
Play Button What sexually transmitted diseases are common in the local populace? Play Button awoH aa rU aa to see wo nee o wo Poo nee aa rE awoH aa raa aBeBe yee? Àwọn aàrùn àtọ̀sì wo ni ó wọ́pọ̀ ní àárín àwọn ará agbègbè yì í?
Play Button What diseases infect local livestock? Play Button awoH aa rU wo nee o maan moo awoH eh roH oo sE? Àwọn aàrùn wo ni ó má a n mú àwọn ẹran ọ̀sìn?
Play Button What sanitation problems affect the local population? Play Button awoH ee daa moo wo nee o waa nee Pa o roo ee mo to to fU awoH aa raa aBeBe yee? Àwọn ìdàmú wo ni ó wà nípa ọ̀rọ̀ ìmọ́tótó fún àwọn ará agbègbè yì í?
Play Button Is there any nuclear, biological or chemical contamination in the area? Play Button shay awoH kaa mee kaa lee taa bee ohn ko tee o lay woo waa nee aBeBe yee? Ṣé àwọn kẹ́míkàlì tàbí nkan tí ó l'éwu wà ní agbègbè yì í?
Go To Main Menu Print Page DLIFLC 2007 previous page PagePage Total next page