Get Instructions
main picture
Title Bar
Go To Main Menu Print Page previous page PagePage Total next page
Play Button Do you know anyone who is employed on the US facility? Play Button shay o mo eh nee yaH ko ko tee o ohn shee sheh nee ee bee o on ee nee aamee ree ka? Ṣé o mọ ènìyàn kankan tí ó n ṣiṣẹ́ ní ibi ohun ìní Amẹ́ríkà?
Play Button Do you know of anyone who works with US forces who has participated in anti-US, anti-coalition, or anti-government protests? Play Button shay o mo ee nee yaH ko ko tee o ohn shee sheh fU awoH o mo o gU aamee ree ka tee o tee nee Pi nee no awoH eh to ee bee no aa oo nee Ba fU aamee ree ka, ee jo ba o ree leh eh day yee aa tee aa jay jee? Ṣé o mọ ènìyàn kankan tí ó n ṣiṣẹ́ fún àwọn ọmọ ogun Amẹ́ríkà tí ó ti níìpín nínú àwọn ètó ìbínú a-ò-nígbà fún Amẹ́ríkà, ìjọba orílẹ̀ èdè yì í àti àjèjì?
Play Button Do you know anyone who is employed on the US facility that has expressed dislike or displeasure toward the US or coalition forces? Play Button shay o mo ee nee yaH ko ko tee o ohn shee sheh fU awoH o mo o gU aamee ree ka tee o tee soo roo ee kU see no nee Pa aamee ree ka taa bee ee jo ba aa jay jee? Ṣé o mọ ènìyàn kankan tí ó n ṣiṣẹ́ fún àwọn ọmọ ogun Amẹ́ríkà tí ó ti sọ̀rọ̀ ìkùnsínú nípa Amẹ́ríkà tàbí ìjọba àjèjì?
Play Button Do you know of anyone who works on a US facility that has been approached by an anti-US or anti-coalition group? Play Button shay o mo ee nee yaH ko ko tee ohn shee sheh fU awoH o mo o gU aamee ree ka tee eh Beh awoH tee o ohn soo roo ee kU see no nee Pa aamee ree ka taa bee ee jo ba aa jay jee ohn ba soo roo? Ṣé o mọ ènìyàn kankan tí ó n ṣiṣẹ́ fún àwọn ọmọ ogun Amẹ́ríkà tí ẹgbẹ́ àwọn tí ó n sọ̀rọ̀ ìkùnsínú nípa Amẹ́ríkà tàbí ìjọba àjèjì n bá sọ̀rọ̀?
Go To Main Menu Print Page DLIFLC 2007 previous page PagePage Total next page